Má ṣe gbàgbé
Àwọn Iṣẹ́ Ìwọlé rẹ!
Kíláàsì 3-5
Ìyẹ̀wò Ìṣesi
Ṣé o nílò láti lo Agbára kan?
Àwọn Àdéhùn Ẹgbẹ́
Ìyẹ̀wò Iṣẹ́
Ilé-ìwé
Ẹbí
Lórí ìwé tí ó tẹ̀ lé e, ìbéèrè kan yóò wà.
Lọ sí apá ibi tí ó ṣàfihàn èrò rẹ nínú yàrá náà.
Fojú inú wo pé ìlà nọ́mbà náà wà kọjá yàrá náà láti 1 sí 10. 1 túmọ̀ sí "Mi ò fẹ́ràn rẹ̀ rárá!" àti 10 túmọ̀ sí "Mo nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ gan-an!"
1
10
Mi ò fẹ́ràn rẹ̀
Mo nífẹ̀ẹ́ rẹ̀
1
2
3
4
5
6
7
8
9
10
1
2
3
4
5
6
7
8
9
10
Mi ò fẹ́ràn rẹ̀
Mo nífẹ̀ẹ́ rẹ̀
Fi ọwọ́ rẹ lé inú rẹ
Mí sínú kí o sì tì inú rẹ jáde
Mí jáde láìkánkán
Àwọn èrò wa ní agbára
A ní Agbára láti yí ohun tí a ń rò padà
Ṣe àṣàrò lórí Agbára Èrò wa
Àwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì rí i pé àwọn ewéko máa ń dàgbà dáadáa tí wọ́n sì máa ń pẹ́ láàyè nígbà tí a bá ń bá wọn sọ̀rọ̀ pẹ̀lú ọ̀yàyà, ṣùgbọ́n wọ́n máa ń rọ tí wọ́n bá sì ń dojú kọ àwọn ọ̀rọ̀ tí kò dára.
Àwọn èrò tí kò ṣànfààní máa ń rẹ̀ ọ́ lẹ́nu bíi "Mo máa ń ṣe àṣìṣe nígbà gbogbo," tàbí "Mi ò níí dára nínú èyí láé."
Àwọn èrò tí ó ṣànfààní máa ń gbé ọ ga, bíi "Mo le ṣe èyí," tàbí "Mo ń gbìyànjú bí mo ṣe le mọ."
Ọpọlọ wa jẹ́ iṣan! A le sọ ọ́ di alágbára nígbà tí a bá ń rò àwọn èrò tí ó ṣànfààní.
Àwọn èrò wa wá láti inú ọpọlọ wa.
Èyí ni Agbára Èrò wa!
Ṣàkíyèsí àwọn èrò tí kò ṣànfààní.
"Ṣé èyí jẹ́ òtítọ́ nígbà gbogbo?", tàbí "Ṣé mo le rò ó ní ọ̀nà mìíràn?"
Gbìyànjú èrò tí ó ṣànfààní jùlọ dípò rẹ̀!
Pinnu èrò wo nínú àwọn tí ó wà nísàlẹ̀ yìí ni ó ṣànfààní àti èyí tí kò ṣànfààní.
Ó ṣànfààní
Kò ṣànfààní
Ó ṣànfààní
Kò ṣànfààní
"Mo nílò ìdánilẹ́kọ̀ọ́ sí i."
"Mi ò dára nínú èyí rárá."
"Wọ́n ń ṣe é mọ̀ọ́mọ̀ láti bí mi nínú."
"Bóyá wọn ò mọ̀ọ́mọ̀ sọ ohun tí wọ́n sọ."
Ó ṣànfààní
Kò ṣànfààní
Ó ṣànfààní
Kò ṣànfààní
Pinnu èrò wo nínú àwọn tí ó wà nísàlẹ̀ yìí ni ó ṣànfààní àti èyí tí kò ṣànfààní.
"Mo le béèrè fún ìrànlọ́wọ́."
"Gbogbo ènìyàn ló dára jù mí lọ."
Ó ṣànfààní
Kò ṣànfààní
Ó ṣànfààní
Kò ṣànfààní
Pinnu èrò wo nínú àwọn tí ó wà nísàlẹ̀ yìí ni ó ṣànfààní àti èyí tí kò ṣànfààní.
Ó ṣànfààní
Ó ṣànfààní
"Ó dára láti ṣe àṣìṣe."
"Mo máa ń ba ohun gbogbo jẹ́."
Pinnu èrò wo nínú àwọn tí ó wà nísàlẹ̀ yìí ni ó ṣànfààní àti èyí tí kò ṣànfààní.
Kò ṣànfààní
Kò ṣànfààní
Ṣé ó jẹ́ òtítọ́ nígbà gbogbo?
Ṣé mo le rò ó ní ọ̀nà mìíràn?
Èrò wo ni ó ṣànfààní jùlọ: 1, 2, tàbí 3?
"Mo rí àmì tí kò dára nínú ìdánwò matimátìkì mi. Mi ò níí ṣe dáadáa láé."
"Mo rí àmì tí kò dára nínú ìdánwò matimátìkì mi. Mi ò níí ṣe dáadáa láé."
Èrò wo ni ó ṣànfààní jùlọ: 1, 2, tàbí 3?
"Mi ò gba bọ́ọ̀lù náà wọlé nínú bọ́ọ̀lù ẹsẹ̀. Mi ò tún fẹ́ ṣe èyí mọ́!"
Èrò wo ni ó ṣànfààní jùlọ: 1, 2, tàbí 3?
Ṣé ó jẹ́ òtítọ́ nígbà gbogbo?
Ṣé mo le rò ó ní ọ̀nà mìíràn?
"Mi ò gba bọ́ọ̀lù náà wọlé nínú bọ́ọ̀lù ẹsẹ̀. Mo máa ń ba eré náà jẹ́ nígbà gbogbo."
Èrò wo ni ó ṣànfààní jùlọ: 1, 2, tàbí 3?
"Èyí kò tọ́ rárá!"
Èrò wo ni ó ṣànfààní jùlọ: 1, 2, tàbí 3?
Ṣé ó jẹ́ òtítọ́ nígbà gbogbo?
Ṣé mo le rò ó ní ọ̀nà mìíràn?
"Ohun búburú kan máa ṣẹlẹ̀. Mo kàn mọ̀ ọ́n ni."
Èrò wo ni ó ṣànfààní jùlọ: 1, 2, tàbí 3?
Kọ Èrò Tí Kò Ṣànfààní kan (láìsí orúkọ) sórí ìwé alámọ̀ọ́lẹ̀.
Fi ìwé alámọ̀ọ́lẹ̀ náà sí àárín ìwé funfun kan.
Ẹ jẹ́ kí a fojú inú wo pé ọ̀rẹ́ kan ti sọ èrò yìí fún wa.
Kọ èrò tí ó ṣànfààní tí wọ́n le rò dípò rẹ̀.
Kọjá ìwé kọ̀ọ̀kan káàkiri títí tí akẹ́kọ̀ọ́ kọ̀ọ̀kan yóò fi kọ Èrò Tí Ó Ṣànfààní kan gẹ́gẹ́ bí ìdáhùn sí Èrò Tí Kò Ṣànfààní kọ̀ọ̀kan.